All Odù with aliases
Èjìogbè
Alias :
Ogbè méjì
Ọ̀yẹ̀kú méjì
Aliases :
Èjì Ọ̀yẹ̀
Ọ̀yẹ̀kú Alápà
Ìwòrì méjì
Alias :
Èjì Ìwòrì
Òdí méjì
Alias :
Èjì Òdí
Ìrosùn méjì
Ọ̀wọ́nrín méjì
Alias :
Èjì Ẹlẹ́rìín
Ọ̀bàrà méjì
Alias :
Èjì Ọ̀bàrà
Ọ̀kànràn méjì
Alias :
Èjì Ọ̀kànràn
Ògúndá méjì
Alias :
Ògúndájì
Ọ̀sá méjì
Alias :
Ọ̀sá Ẹlẹyẹ
Ìká méjì
Òtúrúpọ̀n méjì
Alias :
Ọlọ́gbọ́n méjì
Òtúrá méjì
Aliases :
Òtùá méjì
Èjì Òtùá
Ìrẹtẹ̀ méjì
Alias :
Èjì Ẹlẹ́mẹ̀rẹ̀
Ọ̀ṣẹ́ méjì
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Olúbàdàn
Ọ̀ràngún méjì
Aliases :
Ọ̀ràngún
Òfún méjì
Ogbè Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ogbè Yẹ̀kú
Ogbè Ìwòrì
Aliases :
Ogbè Wẹ̀yìn
Ogbè Wẹ̀yìnwo
Ogbè Òdí
Alias :
Ogbè Dí
Ogbè Ìrosùn
Aliases :
Ogbè Dáwòsùn
Ogbè Ròsùn
Ogbè Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ogbè Húnlé
Ogbè Ọ̀bàrà
Aliases :
Ogbè Gbàràdá
Ogbè Bàrà
Ogbè Ọ̀kànràn
Alias :
Ogbè Kànràn
Ogbè Ògúndá
Alias :
Ogbè Yọ́nú
Ogbè Ọ̀sá
Aliases :
Ogbè Ríkúsá
Ogbè Sá
Ogbè Ìká
Alias :
Ogbè Ká
Ogbè Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ogbè Tọ́mọpọ̀n
Ogbè Òtúrá
Aliases :
Ogbè Alárá
Ogbè Ọlà
Ogbè Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ogbè Atẹ̀
Ogbè Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Ogbè Ṣẹ́
Ogbè Òfún
Aliases :
Ogbè Fohun fólóhun
Ogbè Fùún
Ọ̀yẹ̀kú Ogbè
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Logbè
Ọ̀yẹ̀kú Ìwòrì
Aliases :
Ọ̀yẹ̀kú Pòòrì
Ọ̀yẹ̀kú bÌwòrì
Ọ̀yẹ̀kú wòrì
Ọ̀yẹ̀kú Òdí
Ọ̀yẹ̀kú Ìrosùn
Ọ̀yẹ̀kú Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ọ̀yẹ̀ Wọ́nrin mì
Ọ̀yẹ̀kú Ọ̀bàrà
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Pàlàbà
Ọ̀yẹ̀kú Ọ̀kànràn
Aliases :
Ọ̀yẹ̀kú Pẹlẹ́kàn
Ọ̀yẹ̀kú Fẹlẹ́kànjoyè
Ọ̀yẹ̀kú Ògúndá
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Ọjọ́ Ògúndá
Ọ̀yẹ̀kú Ọ̀sá
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Tẹkú Àṣá
Ọ̀yẹ̀kú Ìká
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Bìká
Ọ̀yẹ̀kú Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Bàtúrúpọ̀n
Ọ̀yẹ̀kú Òtúrá
Aliases :
Ọ̀yẹ̀kú Bẹ̀tùlá
Ọ̀yẹ̀ Òtùá
Ọ̀yẹ̀kú Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú rẹtẹ̀
Ọ̀yẹ̀kú Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ọ̀yẹ̀kú Akinọ̀ṣẹ́
Ọ̀yẹ̀kú ṣẹ́
Ọ̀yẹ̀kú Òfún
Alias :
Ọ̀yẹ̀kú Fùn-ún
Ìwòrì Ogbè
Alias :
Ìwòrì Bogbè
Ìwòrì Ọ̀yẹ̀kú
Ìwòrì Òdí
Alias :
Ìwòrì Wòdí
Ìwòrì Ìrosùn
Alias :
Ìwòrì Gósùn
Ìwòrì Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ìwòrì Ẹlẹ́rìín
Ìwòrì Ọ̀bàrà
Alias :
Ìwòrì Ọ̀bẹ̀rẹ̀
Ìwòrì Ọ̀kànràn
Ìwòrì Ògúndá
Alias :
Ìwòrì Àwẹ̀dá
Ìwòrì Ọ̀sá
Ìwòrì Ìká
Alias :
Ìwòrì Àyọ̀ká
Ìwòrì Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ìwòrì Tútù
Ìwòrì Òtúrá
Aliases :
Ìwòrì Wòtu Pẹ̀rẹ̀pẹ̀
Ìwòrì Òtùá
Ìwòrì Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ìwòrì Wẹrẹ̀
Ìwòrì Ọ̀ṣẹ́
Ìwòrì Òfún
Alias :
Ìwòrìwòfún
Òdí Ogbè
Aliases :
Ìdingbè
Ìdin Gbè
Òdí Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ìdin Yẹ̀kú
Òdí Ìwòrì
Alias :
Ìdin Ìwòrì
Òdí Ìrosùn
Aliases :
Ìdin Ìrosùn
Ìdin Amósùn
Òdí Ọ̀wọ́nrín
Aliases :
Ìdin Ọ̀wọ́nrín
Ìdin arín
Òdí Ọ̀bàrà
Alias :
Ìdin bàrà
Òdí Ọ̀kànràn
Aliases :
Ìdin kànràn
Ìdin Rànyìn
Òdí Ògúndá
Alias :
Ìdin Gúndá
Òdí Ọ̀sá
Aliases :
Ìdin Sàá
Ìdin àṣá
Òdí Ìká
Aliases :
Ìdin Ká
Òdí ká
Òdí Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ìdin túúru
Òdí Òtúrá
Alias :
Ìdin Atàgò
Òdí Ìrẹtẹ̀
Aliases :
Ìdin Ìlẹ̀kẹ̀
Ìdin Òṣogbo
Òdí Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ìdin Ṣẹ́
Ìdin Ṣẹ̀ẹ́
Òdí Òfún
Alias :
Ìdin fùn-ún
Ìrosùn Ogbè
Aliases :
Ìrosùn Agbè
Ìrosùn Akèrègbè
Ìrosùn Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ìrosùn takẹ̀lẹ̀kú
Ìrosùn Ìwòrì
Alias :
Ìrosùn Àwòyè
Ìrosùn Òdí
Alias :
Ìrosùn Dí
Ìrosùn Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ìrosùn Ẹlẹ́rín
Ìrosùn Ọ̀bàrà
Alias :
Ìrosùn Ẹ̀gà
Ìrosùn Ọ̀kànràn
Alias :
Ìrosùn Kànràn
Ìrosùn Ògúndá
Aliases :
Ìrosùn Gẹ́dá
Ìrosùn Gúndá
Ìrosùn Ọ̀sá
Alias :
Ìrosùn Sàá
Ìrosùn Ìká
Alias :
Ìrosùn ká
Ìrosùn Òtúrúpọ̀n
Aliases :
Ìrosùn Tútù
Ìrosùn Ètùtù
Ìrosùn Òtúrá
Aliases :
Ìrosùn Atẹ́rẹ́
Ìrosùn Òtùá
Ìrosùn Ìrẹtẹ̀
Aliases :
Ìrosùn Ọ̀pìnmí
Ìrosùn Atẹ̀
Ìrosùn Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ìrosùn Oṣó
Ìrosùn ṣẹ̀ẹ́
Ìrosùn Òfún
Alias :
Ìrosùn Afin
Ọ̀wọ́nrín Ogbè
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Sogbè
Ọ̀wọ́nrín Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ọ̀wọ́nrín yẹ̀kú
Ọ̀wọ́nrín Ìwòrì
Aliases :
Ọ̀wọ́nrín Wèrè
Ọ̀wọ̀nrín Ọlọ́gbọ́n
Ọ̀wọ́nrín Òdí
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Sìdin
Ọ̀wọ́nrín Ìrosùn
Alias :
Ọ̀wọ́nrín rosùn
Ọ̀wọ́nrín Ọ̀bàrà
Aliases :
Ọ̀wọ́nrín Gbáro
Ọ̀wọ́nrín Bàrà
Ọ̀wọ́nrín Ọ̀kànràn
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Pọ̀kàn
Ọ̀wọ́nrín Ògúndá
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Dàágbọ́n
Ọ̀wọ́nrín Ọ̀sá
Alias :
Ọ̀wọ́nrín sàá
Ọ̀wọ́nrín Ìká
Aliases :
Ọ̀wónrín Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀
Ọ̀wọ́nrín Sìká
Ọ̀wọ́nrín Òtúrúpọ̀n
Aliases :
Ọ̀wọ́nrín Bàtúrúpọ̀n
Ọ̀wọ́nrín bàtú bàtú
Ọ̀wọ́nrín bàjẹ́ lẹ́sẹ̀
Ọ̀wọ́nrín Òtúrá
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Eléjìgbò
Ọ̀wọ́nrín Ìrẹtẹ̀
Aliases :
Ọ̀wọ́nrín Rẹtẹ̀
Ọ̀wọ́n Yánrẹtẹ̀
Ọ̀wọ́nrín Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Wẹsẹ
Ọ̀wọ́nrín Òfún
Alias :
Ọ̀wọ́nrín Wòfún
Ọ̀bàrà Ogbè
Alias :
Ọ̀bàrà Bogbè
Ọ̀bàrà Ọ̀yẹ̀kú
Aliases :
Ọ̀bàrà Yẹ̀go
Ọ̀bàrà Ìnàkí
Ọ̀bàrà Yẹ̀kú
Ọ̀bàrà Ìwòrì
Ọ̀bàrà Òdí
Alias :
Ọ̀bàrà Òbòdí
Ọ̀bàrà Ìrosùn
Alias :
Ọ̀bàrà Kosùn
Ọ̀bàrà Ọ̀wọ́nrín
Ọ̀bàrà Ọ̀kànràn
Alias :
Ọ̀bàrà Kànhìn
Ọ̀bàrà Ògúndá
Alias :
Ọ̀bàrà Ègúntán
Ọ̀bàrà Ọ̀sá
Ọ̀bàrà Ìká
Aliases :
Ọ̀bàrà Ká
Ọ̀bàràǹká
Ọ̀bàrà Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ọ̀bàrà Òtòkú
Ọ̀bàrà Òtúrá
Alias :
Ọ̀bàrà Òtùá
Ọ̀bàrà Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ọ̀bàrà rẹtẹ̀
Ọ̀bàrà Ọ̀ṣẹ́
Ọ̀bàrà Òfún
Alias :
Ọ̀bàrà fùn-ún
Ọ̀kànràn Ogbè
Alias :
Ọ̀kànràn Sodè
Ọ̀kànràn Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ọ̀kànràn Yẹ̀kú
Ọ̀kànràn Ìwòrì
Aliases :
Ọ̀kànràn Ẹgán
Ọ̀kànràn Wórí
Ọ̀kànràn Hìhì
Ọ̀kànràn Òdí
Alias :
Ọ̀kànràn Dí
Ọ̀kànràn Ìrosùn
Alias :
Ọ̀kànràn Rosùn
Ọ̀kànràn Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ọkàn wọ́n-ọ̀n
Ọ̀kànràn Ọ̀bàrà
Alias :
Ọ̀kànràn bàrà
Ọ̀kànràn Ògúndá
Alias :
Ọ̀kànràn Eléégún
Ọ̀kànràn Ọ̀sá
Aliases :
Ọ̀kànràn Sá
Ọ̀kànràn Sálẹ̀ sákùúta
Ọ̀kànràn Ìká
Aliases :
Ọ̀kànràn ká
Ọ̀kànràn kannakánná
Ọ̀kànràn Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ọ̀kànràn Ọjọ́kẹẹ̀dọ́gbọ̀n
Ọ̀kànràn Òtúrá
Alias :
Ọ̀kànràn Òtùá
Ọ̀kànràn Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ọ̀kànràn Rẹtẹ̀
Ọ̀kànràn Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ọ̀kànràn Dàṣẹ́nù
Ọ̀kànràn Adàṣẹ́
Ọ̀kànràn Òfún
Ògúndá Ogbè
Aliases :
Ògúndá Bèdé
Ògúndá Oríire
Ògúndá Ṣogbè
Ògúndá Soríire
Ògúndá Atóríṣe
Ògúndá Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ògúndá Àìkú
Ògúndá Ìwòrì
Alias :
Ògúndá Ara ido
Ògúndá Òdí
Alias :
Ògúndádìí
Ògúndá Ìrosùn
Alias :
Ògúndá Rosùn
Ògúndá Ọ̀wọ́nrín
Aliases :
Ògúndá Ẹ̀rín
Ògúndá Wọ́nrín
Ògúndá Ọ̀bàrà
Alias :
Ògúndá bàrà
Ògúndá Ọ̀kànràn
Ògúndá Ọ̀sá
Aliases :
Ògúndá Mọ́sàá
Ògúndá Sàá
Ògúndá Ìká
Aliases :
Ògúndá Kàá
Ògúndá Ká
Ògúndá Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ògúndá Bàtúrúpọ̀n
Ògúndá Òtúrá
Aliases :
Ògúndá Tẹ̀túálà
Ògúndá Tàṣàá
Ọ̀tá tọ̀tá pa
Ògúndá tàsíá
Ògúndá Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ògúndá kẹtẹ̀
Ògúndá Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ògúndá Làṣẹ
Ògúndá Sẹ̀ẹ́
Ògúndá Òfún
Alias :
Ògúndá Fùn-ún
Ọ̀sá Ogbè
Aliases :
Ọ̀sá Logbè
Ọ̀sá lù fógbè jó
Ọ̀sá Èṣù
Ọ̀sá Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ọ̀sá Yẹ̀kú
Ọ̀sá Ìwòrì
Alias :
Ọ̀sá Wòrì
Ọ̀sá Òdí
Alias :
Ọ̀sá Dí
Ọ̀sá Ìrosùn
Alias :
Ọ̀sá Rosùn
Ọ̀sá Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ọ̀ṣá Onílèfun
Ọ̀sá Ọ̀bàrà
Alias :
Ọ̀ṣá Bàrà
Ọ̀sá Ọ̀kànràn
Alias :
Ọ̀sá Kànràn
Ọ̀sá Ògúndá
Alias :
Ọ̀sá Gùúnlèjà
Ọ̀sá Ìká
Alias :
Ọ̀sá Ká
Ọ̀sá Òtúrúpọ̀n
Ọ̀sá Òtúrá
Aliases :
Ọ̀sá Aláwúre
Ọ̀ sòtítọ́
Ọ̀sá Aláwo
Ọ̀sá Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ọ̀sá Ọ̀lọ́ọ̀yán
Ọ̀sá Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Ọ̀ṣa-à-ṣẹ́
Ọ̀sá Òfún
Alias :
Ọ̀sá fún mi
Ìká Ogbè
Alias :
Ìká Gbèmí
Ìká Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ìká Yẹ̀kú
Ìká Ìwòrì
Ìká Òdí
Alias :
Ìká dìí
Ìká Ìrosùn
Alias :
Ìká Rosùn
Ìká Ọ̀wọ́nrín
Ìká Ọ̀bàrà
Alias :
Ìká bàrà
Ìká Ọ̀kànràn
Aliases :
Ìká kànràn
Ìka kan
Ìká Ògúndá
Alias :
Ìká gúndá
Ìká Ọ̀sá
Alias :
Ìká Sá
Ìká Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ìká Ètùtù
Ìká Òtúrá
Alias :
Ìká Òtùá
Ìká Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ìká Rẹtẹ̀
Ìká Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Ìkaà Sẹ́
Ìká Òfún
Alias :
Ìká Fún
Òtúrúpọ̀n Ogbè
Alias :
Òtúrúpọn Gbè
Òtúrúpọ̀n Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Òtúrúpọ̀n yẹ̀kú
Òtúrúpọ̀n Ìwòrì
Aliases :
Òtúrúpọ̀n Làwì
Òtúrúpọ̀n Làwòrì
Òtúrúpọ̀n Òdí
Alias :
Òtúrúpọ̀n Dìí
Òtúrúpọ̀n Ìrosùn
Alias :
Òtúrúpọ̀n Sokùn
Òtúrúpọ̀n Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Òtúrúpọ̀n Ọbàlùfọ̀n
Òtúrúpọ̀n Ọ̀bàrà
Alias :
Òtúrúpọ̀n dàrà
Òtúrúpọ̀n Ọ̀kànràn
Alias :
Òtútù Pọ̀kànràn
Òtúrúpọ̀n Ògúndá
Aliases :
Òtúrúpọ̀n Gúndá
Òtúrúpọ̀n Gede
Òtúrúpọ̀n Ọ̀sá
Alias :
Òtúrúpọ̀n Sá
Òtúrúpọ̀n Ìká
Alias :
Òtúrúpọ̀n Ká
Òtúrúpọ̀n Òtúrá
Alias :
Òtúrúpọ̀n túwúrẹ́
Òtúrúpọ̀n Ìrẹtẹ̀
Òtúrúpọ̀n Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Òtúrúpọ̀n Dáṣẹ́kẹ́
Òtúrúpọ̀n Òfún
Alias :
Òtúrúpọ̀n fún
Òtúrá Ogbè
Aliases :
Òtùá Oríre
Òtúrá Ṣoríire
Òtùá Oríkọ̀
Òtùá Ẹkúndayọ̀
Òtùá Orígbèmí
Òtúrá Ọ̀yẹ̀kú
Aliases :
Òtúrá Bùyẹ̀
Òtúrá Yẹ̀pín
Òtúrá Ọpọ́n kan
Òtùá yànpín
Òtúrá Ìwòrì
Alias :
Òtùá Olóhùnwò
Òtúrá Òdí
Alias :
Òtùá dí
Òtúrá Ìrosùn
Alias :
Òtùá Amósùn
Òtúrá Ọ̀wọ́nrín
Aliases :
Òtùá Ìmẹ́lẹ́
Òtùá Mẹ̀ẹ́lẹ́
Òtùá Alákétu
Òtúrá Ọ̀bàrà
Alias :
Òtùá Àràbà
Òtúrá Ọ̀kànràn
Alias :
Òtùá kànràn
Òtúrá Ògúndá
Aliases :
Òtùá Rerá
Òtùá Rirá
Òtùá Ègúntán
Òtúrá Ọ̀sá
Aliases :
Òtùá Gásàá
Òtùá Sàá
Òtúrá Ìká
Alias :
Òtùá ká
Òtúrá Òtúrúpọ̀n
Alias :
Òtùá Òtúrúpọ̀n
Òtúrá Ìrẹtẹ̀
Alias :
Òtùá rẹtẹ̀
Òtúrá Ọ̀ṣẹ́
Alias :
Òtùá Dàṣẹ́nù
Òtúrá Òfún
Alias :
Òtùá Ẹlẹfun
Ìrẹtẹ̀ Ogbè
Aliases :
Ìrẹ́ńtẹgbè
Àtẹ̀ gbè
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ìrẹtẹ̀ yẹ̀kú
Ìrẹtẹ̀ Ìwòrì
Ìrẹtẹ̀ Òdí
Alias :
Ìrẹtẹ̀ Dí
Ìrẹtẹ̀ Ìrosùn
Aliases :
Atẹ̀ nínú ìlosùn
Atẹ̀núlosùn
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ìrẹtẹ̀ Ọlọ́tà
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀bàrà
Aliases :
Ìrẹtẹ̀ Ọba
Ìrẹtẹ̀ Àlàó
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀kànràn
Alias :
Ìrẹtẹ̀ Kànlù
Ìrẹtẹ̀ Ògúndá
Aliases :
Ìrẹtẹ̀ Àáyá
Ìrẹtẹ̀ a pẹ́ lóko
Ìrẹtẹ̀ Ọdúnjọ
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀sá
Alias :
Ìrẹtẹ̀ Sá
Ìrẹtẹ̀ Ìká
Aliases :
Ìrẹtẹ̀ Ká
Àtẹ̀ Ká
Ìrẹtẹ̀ Òtúrúpọ̀n
Alias :
Ìrẹtẹ̀ Tútù
Ìrẹtẹ̀ Òtúrá
Aliases :
Ìrẹtẹ̀ Ẹṣẹ̀ kan ọlà
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀tún
Ìrẹtẹ̀ Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Ìrẹtẹ̀ Alájé
Ìrù Ẹkùn
Ìrẹtẹ̀ Òfún
Alias :
Àtẹ̀ fún
Ọ̀ṣẹ́ Ogbè
Aliases :
Ọ̀ṣẹ́ Orógbè
Ọ̀ṣẹ́ Logbè
Ọ̀ṣẹ́ Ọ̀yẹ̀kú
Alias :
Ọ̀ṣẹyẹ̀kú
Ọ̀ṣẹ́ Ìwòrì
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Ìmùlẹ̀
Ọ̀ṣẹ́ Òdí
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Dìí
Ọ̀ṣẹ́ Ìrosùn
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Olósùn
Ọ̀ṣẹ́ Ọ̀wọ́nrín
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Oníwọ
Ọ̀ṣẹ́ Ọ̀bàrà
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Bàrà
Ọ̀ṣẹ́ Ọ̀kànràn
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Kànràn
Ọ̀ṣẹ́ Ògúndá
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Òmólú
Ọ̀ṣẹ́ Ọ̀sá
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Sá
Ọ̀ṣẹ́ Ìká
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ Kàá
Ọ̀ṣẹ́ Òtúrúpọ̀n
Ọ̀ṣẹ́ Òtúrá
Aliases :
Ọ̀ṣẹ́ Tùá
Ọ̀ṣẹ́ Awúrelà
Ọ̀ṣẹ́ Ìrẹtẹ̀
Alias :
Ọ̀ṣẹ́ bìrẹtẹ̀
Ọ̀ṣẹ́ Òfún
Òfún Ogbè
Alias :
Òfún Nagbè
Òfún Ọ̀yẹ̀kú
Aliases :
Òfún Ajítẹnà
Òfún Tẹnà
Òfún Ìwòrì
Òfún Òdí
Alias :
Òfún dìí
Òfún Ìrosùn
Alias :
Òfún Orósùn
Òfún Ọ̀wọ́nrín
Òfún Ọ̀bàrà
Alias :
Òfún Bàrà
Òfún Ọ̀kànràn
Alias :
Òfún Ọlọ̀kànràn
Òfún Ògúndá
Òfún Ọ̀sá
Alias :
Òfún Sàá
Òfún Ìká
Òfún Òtúrúpọ̀n
Alias :
Òfún Arídẹgbé
Òfún Òtúrá
Aliases :
Òfún Tọ̀ọ́lá
Òfún Òtùá
Òfún Ìrẹtẹ̀
Alias :
Òfún rẹtẹ̀
Òfún Ọ̀ṣẹ́
Aliases :
Òfún Onílẹ̀ẹ́ṣẹ́
Òfún ṣẹ̀ẹ́